Ìgbà Òṣèlú Èkejì Nàìjíríà
(Àtúnjúwe láti Nigerian Second Republic)
Ìgbà Òṣèlú Elékejì Nàìjíríà tàbì Orílẹ̀-èdè Olómìnira ará Nàìjíríà Èkejì jẹ́ ìgbà ìṣèjọba àwarawa àwọn mẹ̀kúnnù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó wáyé láàrin ọdún 1979 sí 1983 tí ó jẹ́ ìṣèjọba pẹ̀lú ìlànà-ìbágbépọ̀ kejì asominira.
Awon Aare[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
President | Term | Party |
---|---|---|
Shehu Shagari | October 1, 1979 - December 31, 1983 | NPN |
Awon egbe oloselu[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- Greater Nigerian People's Party (GNPP)
- National Party of Nigeria (NPN)
- Nigeria Advance Party (NAP)
- Nigerian People's Party (NPP)
- People's Redemption Party (PRP)
- Unity Party of Nigeria (UPN)
Awon Gomina[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |