Àsìá ilẹ̀ Nàìjíríà
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Flag of Nigeria)
Use | National flag Fáìlì:FIAV Equal.svg Fáìlì:FIAV Vertical unknown.svg |
---|---|
Proportion | 1:2 |
Adopted | Oṣù Kẹ̀wá 1, 1960 |
Design | A vertical bicolour triband of green, white and green. |
Designed by | Michael Taiwo Akinkunmi |
Variant flag of Federal Republic of Nigeria | |
Use | State flag |
Proportion | 1:2 |
Design | A vertical bicolour triband of a green, white and green; charged with the coat of arms in the centre. |
Variant flag of Federal Republic of Nigeria | |
Use | Civil ensign Fáìlì:FIAV Mirror.svg |
Proportion | 1:2 |
Design | A red field with the national flag, in the canton |
Variant flag of Federal Republic of Nigeria | |
Use | State ensign |
Proportion | 1:2 |
Design | A blue field with the national flag, in the canton |
Variant flag of Federal Republic of Nigeria | |
Use | Naval ensign Fáìlì:FIAV Mirror.svg |
Proportion | 1:2 |
Design | A white field with the national flag in the canton, with the Naval seal in the fly. |
Variant flag of Federal Republic of Nigeria | |
Use | Air force ensign Fáìlì:FIAV Mirror.svg |
Proportion | 1:2 |
Design | A sky-blue field with the national flag in the canton, with the air force roundel in the fly. |
Àsíá ilẹ̀ Nàìjíríà tí Michael Taiwo Akinkunmi ṣe ní wọ́n gbà wọlé gẹ́gẹ́ bí i èyí tó máa ṣojú Nàìjíríà láti òru ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1960, ọjọ́ tí Nàìjíríà gba òmìnira. Wọ́n fi ọ̀rọ̀ àsíá yìí ṣe ìdíje, tí àwọn ènìyàn ẹgbẹ̀rún mẹ́tà sì dá sí. Àsíá tí Akinkunmi ṣe ni wọ́n gba wọlé láàárín àwọn èyí tí gbogbo àwọn tó kópa nínú ìdíje náà ṣe. Àwọ̀ àsíá náà jẹ́ aláwọ̀ ewé-funfun-aláwọ̀ ewé, tí aláwọ̀-ewé náà dúró fún iṣẹ́-àgbè, tí funfun sì dúró fún àlàáfíà àti ìṣọ̀kan.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |