Alex Ekwueme

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Alex Ifeanyichukwu Ekwueme)
Igbákejì Ààre Alex Ifeanyichukwu Ekwueme láti orílè-èdè Nàìjíríà ni a kí káàbò nígbàtí ó dé fún àbèwò sí Améríkà.
Alex Ekwueme

Alex Ifeanyichukwu Ekwueme (ojoibi October 21, 1932) je oloselu ati Igbakeji Aare ile Naijiria si Aare Shehu Shagari ni Igba Oselu Keji lati 1979 de 1983.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]