Túndé Ìdíàgbọn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Tunde Idiagbon)
Jump to navigation Jump to search
Babatunde Idiagbon
6th Chief of Staff, Supreme Headquarters
Lórí àga
31 December 1983 – 27 August 1985
Ààrẹ Muhammadu Buhari as Military Head of State
Asíwájú Alex Ekwueme as civilian Vice President of Nigeria
Arọ́pò Ebitu Ukiwe
Governor of Borno State
Lórí àga
July 1978 – October 1979
Asíwájú Mustapha Amin
Arọ́pò Mohammed Goni
Personal details
Ọjọ́ìbí (1942-09-14)14 Oṣù Kẹ̀sán 1942
Ilorin, Kwara, Nigeria
Aláìsí 24 March 1999(1999-03-24) (ọmọ ọdún 56)
Ilorin, Kwara, Nigeria
Nationality Nigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlu None (military)
Spouse(s) Biodun Idiagbon
Alma mater Nigerian Military School
Pakistan Military Academy
Nigerian Defence Academy
Naval Postgraduate School
Military service
Allegiance  Nigeria
Service/branch  Adigun Nàìjíríà
Years of service 1962–1985
Rank Major General

Babatunde Baku Abdul Idiagbon (14 September 1942 - 24 March 1999) jẹ́ ọmọ ológun ará ilẹ̀ Naijiria. Ní ọdún 1983 ó kópa nínú ifipágbàjoba lọ́wọ́ Ààrẹ Shehu Shagari, lẹ́yìn èyí ó di Ọ̀gá Gbogbo Ọmọṣẹ́ ológun ní ibùjókó tógajùlọ ní I Ológun ilẹ̀ Nàìjíríà, ipò yí dúró gẹ́gẹ́ bí igbákejì ààrẹ sí Muhammadu Buhari tó di ààrẹ orílẹ̀-èdè. Idiagbon di ipò yí mú lati 31 December, 1983 titi di 27 August, 1987 ti Ibrahim Babangida náà fi fipágbàjoba.[1]


Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Inamete, Ufot (2001). Foreign Policy Decision-making in Nigeria. Susquehanna University Press. pp. 131.