Kashim Shettima

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kashim Shettima
Kashim Shettima - Sambisa Forest, 2017.png
Kashim Shettima, gómìna Ìpínlẹ̀ Borno tẹ́lẹ̀
Gomina Ipinle Borno
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 May 2011
AsíwájúAli Modu Sheriff
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí2 Oṣù Kẹ̀sán 1966 (1966-09-02) (ọmọ ọdún 56)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress (APC)

Kashim Shettima (ojoibi 2 September 1966) je aseitookowo oniseagbe ara Nàìjíríà to je didiboyan bi Gomina Ipinle Borno, Nigeria ninu idiboyan 26 April 2011 labe asia egbe oloselu All Nigeria People's Party (ANPP). oun ni oludije fun igbakeji aare egbe naa ninu idibo aare odun 2023 ti o n dije pelu Bola Tinubu lábé egbé òsèlú all progressive congress(APC).Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]