Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Delta State)
Jump to navigation Jump to search
Ìpínlẹ̀ Delta
State nickname: The Big Heart
Location
Location of Delta State in Nigeria
Statistics
Governor
(List)
Emmanuel Uduaghan (PDP)
Date Created 27 August 1991
Capital Asaba
Area 17,698 km²
Ranked 23rd
Population
1991 Census
2005 estimate
Ranked 9th
2,570,181
4,710,214
ISO 3166-2 NG-DE

Ipinle Delta je ipinle kan nini awon Ipinle ni orile-ede Naijiria. Ìpínlè Delta wà ní apa Guusu Nàìjíríà. Adá Ìpínlè Delta kalè ní ojo ketadinlogbon, osu kejo, odun 1991(27, August 1991) ní abe isejoba Gen. Ibrahim Babangida [1]. Olú-ìlú Ìpínlè Delta ní Asaba bí otile jepe ìlú Warri ìkan aje/oja kale sí jù. Àwon èyà tí opoju ní Ìpinlè Delta ni Igbo, Urhobo, Isoko, Ijaw, Itsekiri [2]. Ìpinlè Delta ní Ìjoba Agbegbe Ibile marundinlogbon(25) [3]

Awon Ìjoba Agbegbe Ìbílè ti Delta[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

• Aniocha North • Aniocha South • Bomadi • Burutu • Ethiope South • Ethiope east • Ika North East • Ika South • Isoko North • Isoko South • Ndokwa east • Ndokwa west • Okpe • Oshimili North • Oshimili South • Patani • Sapele • Udu • Ughelli North • Ughelli South • Ukwuani • Uvwie • Warri North • Warri South • Warri South WestItokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Brief History of Delta State:: Nigeria Information & Guide". Nigeriagalleria. 1991-08-27. Retrieved 2022-03-26. 
  2. "Delta State, Nigeria Genealogy". FamilySearch Wiki. 2020-04-11. Retrieved 2022-03-26. 
  3. "Local Government Areas in Delta State". Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria. Retrieved 2022-03-26.