Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Oyo State | |
---|---|
Nickname(s): | |
![]() Location of Ọyọ State in Nigeria | |
Coordinates: 8°00′N 4°00′E / 8.000°N 4.000°ECoordinates: 8°00′N 4°00′E / 8.000°N 4.000°E[2] | |
Country | ![]() |
Date created | 3 February 1976 |
Capital | Ibadan |
Government | |
• Governor[3] | Oluwaseyi Makinde (PDP) |
• Deputy Governor | Rauf Olaniyan |
• Senators | Abdulfatai Buhari Kola Balogun Teslim Folarin |
• Representatives | List |
Area | |
• Total | 28,454 km2 (10,986 sq mi) |
Population (2006)[4] | |
• Total | 5,580,894[1] |
GDP | |
• Year | 2007 |
• Total | $29.8 billion[5] |
• Per capita | $2,666[5] |
Time zone | UTC+01 (WAT) |
ISO 3166 code | NG-OY |
HDI (2016) | 0.440[6] · 22nd of 36 |
Website | oyostate.gov.ng |
Ìpínlẹ̀ Oyo jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìpínlẹ̀ Mẹ́rìndínlógójì tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ yí wà ní Ìwọ̀ Oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí olú ìlú rẹ̀ sì fìdí kalẹ̀ sí ìlú Ìbàdàn, tí olú ìlú rẹ̀ sí jẹ́ ìlú kẹta tí ó lérò púpò julọ ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí o si figbakan je ìlú Kejì tó lérò púpò julọ ní Áfríkà ri. A dá ìpínlè e Ọ̀yọ́ sílè ní ọjọ́ kẹta oṣù kejì ọdún 1976. Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ jẹ́ ìpínlè kaarun ti èrò pọ julọ sí ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Púpọ̀ nínu àwọn ará ìpínlè Ọ̀yọ́ jẹ́ Yorùbá, ti èdè Yorùbá sì jẹ èdè tí wọ́n n sọ julọ ní ìpínlè náà.
Ṣèyí Mákindé jẹ́ gómìnà ìpínlẹ́ Ọ̀yọ́.
Àwọn agbègbè ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ìpínlẹ́ Ọ̀yọ́ ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Mẹ́tàlélọ́gbọ̀n. Awon ni:(E tun wo awon AII Naijiria)
Ilé ẹ̀kọ́ gíga[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Awọn ilé ẹ̀kọ́ gíga wọ̀nyí ni wón wa ni ìpínlè Oyo;[7]
- University of Ibadan, Ibadan
- Ladoke Akintola University of Technology, Ogbomoso
- Lead City University, Ibadan
- Dominican University, Ibadan
- Ajayi Crowther University, Oyo
- Koladaisi University
- Oyo State Technical University, Ibadan, Oyo State
- Àtìbà University, Ọ̀yọ́
- The Polytechnic, Ibadan
- Adeseun Ogundoyin Polytechnic, Eruwa
- The Oke-Ogun Polytechnic
- Federal Polytechnic Ayede, Ogbomoso
- Federal School of Surveying, Oyo
- Federal College of Forestry, Ibadan
- Federal College of Agriculture, Ibadan
- Federal Cooperative College, Ibadan
- Federal School of Statistics, Ibadan
- Federal College of Education (Special), Oyo
- Federal College of Animal Health and Production Technology, Moor plantation Ibadan (FCAHPT)
- Federal College of Agriculture Ibadan
- Emmanuel Alayande College of Education
- Oyo State College of Agriculture and Technology, Igbo-Ora
- Oyo State College Of Nursing and Midwifery, Eleyele, Ibadan
- Oyo State College of Health Science and Technology, Eleyele, Ibadan
- The College of Education, Lanlate.
- The Kings Polytechnic, Saki
- SAF Polytechnic, Iseyin
- City Polytechnic, Ibadan
- Tower Polytechnic, Ibadan
- Bolmor Polytechnic, Ibadan
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ "2006 PHC Priority Tables – NATIONAL POPULATION COMMISSION". population.gov.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-10-10.
- ↑ The Encyclopedia of African-American Heritage by Susan Altman , Chapter O, page 183
- ↑ See List of Governors of Oyo State for a list of prior governors
- ↑ [1] State overview
- ↑ 5.0 5.1 "C-GIDD (Canback Global Income Distribution Database)". Canback Dangel. Retrieved 2015-08-20.
- ↑ "National Human Development Report 2018" (PDF).
- ↑ "List of Universities in Oyo State". www.myschoolgist.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-11-04. Retrieved 2021-06-03.