Abass Akande Obesere

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Abass Àkàndé Òbésèré
Birth name Abass Akande
Also known as Omo Rapala, Papa Tosibe, Sidophobia
Born January 28 1965 (ọmọ ọdún 54–55)
Ibadan, Oyo State, Nigeria
Genres
Occupations Singer-songwriter
Instruments Vocals
Years active 1981–present
Labels
  • Freeworld Music[1][2]
  • Mayors Veil Entertainment
  • Sony Music
  • Bayowa Records

Abass Àkàndé Òbésèré tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ọmọ Rápálá (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejìndínlọ́gbọ̀n, oṣù kìíní ọdún 1965) jẹ́ gbajúmọ̀ olórin Fújì ọmọ bíbí ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ìràwọ̀ Òbésèré tán nípa orin alùfàǹṣá Fújì tí ó máa ń kọ. Orin Àṣàkáṣà ní ó pọ̀jù nínú àwọn orin Fújì rẹ̀, kódà, ó pe ara rẹ̀ ní Ọba Àṣàkáṣà nínú àwo rẹ̀ kan.[3] [4]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]