Ibadan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ibadan
ìlú ńlá
Ìlú Ìbàdàn látòkèrè (Oṣù kẹwá ọdún 2016)
Ìlú Ìbàdàn látòkèrè (Oṣù kẹwá ọdún 2016)
Ìnagijẹ: Ile Oluyole Ilu Ogunmola
Ibadan is located in Nigeria
Ibadan
Ibadan
Location in Nigeria
Coordinates: 7°23′47″N 3°55′0″E / 7.39639°N 3.916667°E / 7.39639; 3.916667Àwọn Akóìjánupọ̀: 7°23′47″N 3°55′0″E / 7.39639°N 3.916667°E / 7.39639; 3.916667
Country  Nigeria
State Oyo
War camp 1829
Ibadan District Council 1961
Ibadan Municipal Government 1989
Ìjọba
 • Olubadan Oba Saliu Akanmu Adetunji
Ìtóbi
 • ìlú ńlá 3,080 km2 (1,190 sq mi)
 • Urban 6,800 km2 (2,600 sq mi)
Area rank 1st
Agbéìlú (2006)[2]
 • ìlú ńlá 2,559,853
 • Estimate (2011) 3,034,200
 • Rank 3rd
 • Density 985.13/km2 (2,551.5/sq mi)
 • Ìgboro 3,160,000[1]
 • Ìgboro density 464.71/km2 (1,203.6/sq mi)
 • Metro 3,500,000 (estimated)
Time zone WAT (UTC+1)
Climate Tropical savanna climate (Aw)
Website http://www.oyostate.gov.ng/

íbádán jẹ̀ olu-ilu ati ibi ti eniyan po si julo ni Ipinle Oyo ti o wa ni orile-ede Nàìjíríà. Pelu awon olugbe ti o le ni millionu meta, ipo keta ni ilu Ibadan wa ti a ba ka awon ilu ilu ti eniyan po si julo ni ilu Naijiria, o nto ilu Eko ati Kano leyin; Ibadan ni ilu ti o tobi julo ni iwon. Ni akoko ti orile-ede Naijiria gba ominira, Ibadan ni ilu ti o tobi ju ti olugbe inu re si po julo, oun si ni ilu ti olugbe inu re po sikeji ni ile alawo dudu Afrika, leyin Kairo.

Ibadan wa ni apa gusu-iwo-oorun Naijiria, iwon re je kilomita meji-din-laadoje lati ariwa-ila-oorun ilu Eko ati iwon kilomita eedegbeta-le-logbon lati guusu-iwo-oorun ilu Abuja, ti o je olu-ilu ile Naijiria, eleyi ti o je pataki ti a ba fe koja lati awon erekusu si aarin gbungbun ile Naijiria. Ibadan ti wa ni gbangba ise'joba lati igba Agbegbe Iwo-oorun ni akoko ijoba amunisin awon oyinbo alawo funfun, lara awon odi ti a fi se aabo fun ilu naa si wa sibe di oni yi. Awon eya ti a n pe ni Yorubas ni o po julo ninu awon olugbe ilu Ibadan, nigbati awon eya lati oniruuru agbegbe jake jado orile-ede Naijiria si ngbe ninu ilu Ibadan bakanna.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Demographia (January 2015). Demographia World Urban Areas (11th ed.). http://www.demographia.com/db-worldua.pdf. Retrieved 2 March 2015. 
  2. Summing the 11 Local Government Areas of Ibadan using:
    population.de (2011). "Population of oyo state". Retrieved 15 July 2016.