Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù-Ìlàòrùn Ìbàdàn
Ìrísí
Ibadan South-East | |
---|---|
Country | Nigeria |
State | Oyo State |
Government | |
• Local Government Chairman and the Head of the Local Government Council | Emmanuel Oluwole Alawode (PDP) |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù-Ìlàòrùn Ìbàdàn jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ní Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ wà ní gbọ̀ngán Mapo. Kóòdù ìfìwéránṣẹ́ ìlú náà ni 200.[1]
Ìwọ̀n ilẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó ní ìwọ̀n ilẹ̀ tó tó 17 km2 àti iye ènìyàn tó tó 266,046 ní ìka orí tó wáyé ní ọdún 2006.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)