Yola
Ìrísí
Yola di olú-ìlú àti ìlú tí ó tóbi jù ní f Ìpínlẹ̀ Adamawa, Nàìjíríà. Ìlú náà wà ní olùgbé 336,648 ní ọdun 2010.[1] Yola pín sí méjì, àwọn ni ìlú Yola àtijó níbi tí Lamido ìlú náà gbé àti ìlú Jimeta, ìlú Jimeta ní àárín ètò ọ̀rọ̀ ajé Yola.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
9°14′N 12°28′E / 9.23°N 12.46°E
Àwọn Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Yola | Hometown.ng™" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-31. Retrieved 2021-06-25.