Òṣogbo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Òṣogbo
Location of Osogbo in Nigeria

Òṣogbo jẹ́ ìlú ńlá kan ní ìpílẹ̀ Ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, bákan náà ni ó jẹ́ olú ìlú fún ìpínlẹ̀ náà pẹ̀lú ní apá ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.

7°46′N 4°34′E / 7.767°N 4.567°E / 7.767; 4.567