Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ọsun State
State
Osun river in Osogbo, Osun state
Osun river in Osogbo, Osun state
Ìnagijẹ: State of the Living Spring
Location of Ọsun State in Nigeria
Location of Ọsun State in Nigeria
Country  Nigeria
Date created 27 August 1991
Capital Osogbo
Ìjọba
 • Governor[1] Rauf Aregbesola (ACN)
Ìtóbi
 • Total 9,251 km2 (3,572 sq mi)
Area rank 28th of 36
Agbéìlú (1991 census)
 • Total 2,203,016
 • Estimate (2005) 4,137,627
 • Rank 17th of 36
 • Density 240/km2 (620/sq mi)
GDP (PPP)
 • Year 2007
 • Total $7.28 billion[2]
 • Per capita $2,076[2]
Time zone WAT (UTC+01)
ISO 3166 code NG-OS

Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun je okan ninu awon Ipinle ni orile-ede Naijiria. Ipinle Osun je ipinle arin ile ni apa gusu-iwoorun Naijiria. Olu-ilu re ni ilu Osogbo. O ni ibode ni ariwa mo Ipinle Kwara, ni ila-oorun die mo Ipinle Ekiti ati die mo Ipinle Ondo, ni guusu mo Ipinle Ogun ati ni iwoorun mo Ipinle Oyo. Gomina ipinle na lowolowo bayi ni Gomina Gboyega Oyetola.[3] Won dibo yan-an wole ni 2018.[4] Osun ni ibi ti opo awon ibi meremere to gbajumo wa, lopo mo ogba Yunifasiti Obafemi Awolowo to wa ni Ile-Ifẹ, ibi to se pataki ninu asa Yoruba. Awon ilu tose pataki ni ipinle Osun tun ni Oke-Ila Orangun, Ila Orangun, Ede, Iwo, Ejigbo, Esa-Oke and Ilesa.

Itan[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Osun river in Osogbo, Osun state

Ipinle Osun gege bi ipinle amojuto ijoba je dida sile ni odun 1991 lati apa Ipinle Oyo atiyo. Oruko re wa lati Odo Osun.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. See List of Governors of Osun State for a list of prior governors
  2. 2.0 2.1 "C-GIDD (Canback Global Income Distribution Database)". Canback Dangel. Retrieved 2008-08-20. 
  3. "Supreme Court affirms Gboyega Oyetola's election as Osun Governor". Premium Times Nigeria. 2019-07-05. Retrieved 2019-09-18. 
  4. "Appeal Court say Oyetola win Osun election". BBC News Pidgin. 2019-05-09. Retrieved 2019-09-18.