Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ipinle Osun)
Jump to navigation Jump to search
Ọsun State
State
Osun river in Osogbo, Osun state
Osun river in Osogbo, Osun state
Ìnagijẹ: State of the Living Spring
Location of Ọsun State in Nigeria
Location of Ọsun State in Nigeria
Country  Nigeria
Date created 27 August 1991
Capital Osogbo
Ìjọba
 • Governor[1] Rauf Aregbesola (ACN)
Ìtóbi
 • Total 9,251 km2 (3,572 sq mi)
Area rank 28th of 36
Agbéìlú (1991 census)
 • Total 2,203,016
 • Estimate (2005) 4,137,627
 • Rank 17th of 36
 • Density 240/km2 (620/sq mi)
GDP (PPP)
 • Year 2007
 • Total $7.28 billion[2]
 • Per capita $2,076[2]
Time zone WAT (UTC+01)
ISO 3166 code NG-OS

Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun je ikan ninu awon Ipinle ni orile-ede Naijiria. Ipinle Osun je ipinle arin ile ni apaguusu-iwoorun Naijiria. Oluilu re ni ilu Osogbo. O ni bode ni ariwa mo Ipinle Kwara, ni ilaorun die mo Ipinle Ekiti ati die mo Ipinle Ondo, ni guusu mo Ipinle Ogun ati ni iwoorun mo Ipinle Oyo. Gomina ipinle na lowolowo bayi ni Rauf Aregbesola, to wole pelu ibo ni 2010 pelu Igbakeji Gomina. Osun ni ibi ti opo awon landmark to gbajumo wa, lopo mo ogba Yunifasiti Obafemi Awolowo to wa ni Ile-Ifẹ, ibi to se pataki ninu asa Yoruba. Awon ilu tose pataki ni ipinle Osun tun ni Oke-Ila Orangun, Ila Orangun, Ede, Iwo, Ejigbo, Esa-Oke and Ilesa.

Itan[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Osun river in Osogbo, Osun state

Ipinle Osun gege bi ipinle amojuto ijoba je dida sile ni odun 1991 lati apa Ipinle Oyo atiyo. Oruko re wa lati Odo Osun.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. See List of Governors of Osun State for a list of prior governors
  2. 2.0 2.1 "C-GIDD (Canback Global Income Distribution Database)". Canback Dangel. Retrieved 2008-08-20.