Jump to content

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìlàòrùn Ilesa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ilesa East
Country Nigeria
StateOsun State
Government
 • Local Government Chairman and the Head of the Local Government CouncilLanre Balogun
Area
 • Total71 km2 (27 sq mi)
Population
 (2006 census)
 • Total106,586
Time zoneUTC+1 (WAT)
3-digit postal code prefix
233
ISO 3166 codeNG.OS.IH

Ìlà Oòrùn Iléṣà jẹ́ agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣunNaijiria. Olú ilé ìjọba ìbílẹ̀ náà wà ní Iyemogun ni ìlú Ilésà. Agbègbè náà tóbi tó 71 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ 106,586 nígbà ìkànìyàn ọdún 2006. Kóòdù ìfìwéránṣé agbègbè yí sì jẹ́ 233.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2009-10-07. Retrieved 2009-10-20.