Jump to content

Rauf Aregbesola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Rauf Aregbesola
Gomina Ipinle Osun
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
27 November 2010
AsíwájúOlagunsoye Oyinlola
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí25 Oṣù Kàrún 1957 (1957-05-25) (ọmọ ọdún 67)
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAction Congress of Nigeria

Rauf Aregbesola A bí i ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 1957. Ó jẹ́ àgbà olósèlú ọmọ ilẹ̀ Yorùbá láti ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun orílẹ̀-èdè Nàíjíríà. Wọ́n dìbò yàn-án gẹ́gẹ́ bí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun ní ọdún 2010 títí ó fí fipò náà Sílẹ̀ ní ọdún 2018 lẹ́yìn tó lo sáà kejì rẹ̀ tán. Gboyega Oyetola ni Rauf Arẹ́gbẹ́ṣolá fa agbára Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lé lọ́wọ́ lẹ́yìn sáa rẹ̀[1] ní ọdún 2019, olórí orílẹ̀-èdè Muhammadu Buhari yàn-án gẹ́gẹ́ bí Mínísítà alábòjútó ètò abẹ́lé (Minister for Interior) orílẹ̀-èdè Nàìjíríà[2]


  1. "My successor, Oyetola, doesn't have my 'swagger' - Aregbesola - Premium Times Nigeria". Premium Times Nigeria. 2018-11-17. Retrieved 2019-09-20. 
  2. Bankole; Bankole (2019-08-21). "Profile of Interior Minister, Ogbeni Rauf Aregbesola". Vanguard News. Retrieved 2019-09-20.