Godswill Akpabio

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Godswill Obot Akpabio
Governor of Akwa Ibom State
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 May 2007
AsíwájúObong Victor Attah
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí19 Oṣù Kejìlá 1962 (1962-12-19) (ọmọ ọdún 61)
Ukana, Ikot Ntuem, Akwa Ibom State, Nigeria

Godswill Akpabio jẹ́ agbẹjọ́rò àti olósèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Naijiria, ohùn ni Ààrẹ ilé ìgbìmò Asòfin lọ́wọ́lọ́wọ́,[1][2] òun sì ni Gómìnà Ipinle Akwa Ibom láti ọdún 2007 títí di ọdún 2015.[3]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Oyero, Kayode (13 June 2023). "UPDATED: Akpabio Sworn In As Senate President". Channels Television. Retrieved 13 June 2023. 
  2. Obeme-Ndukwe, Ifunanya (13 June 2023). "Akpabio elected Senate President". Daily Post Nigeria. Retrieved 13 June 2023. 
  3. "Enough is enough". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-07-30. Retrieved 2022-02-22.