Tunde Ogbeha

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jonathan Tunde Ogbeha
Governor of Akwa Ibom State
In office
28 September 1987 – 30 July 1988
Arọ́pòGodwin Abbe
Governor of Bendel State
In office
Dec 1987 – Aug 1990
AsíwájúJohn Mark Inienger
Arọ́pòJohn Ewerekumoh Yeri
Senator - Kogi West
In office
May 1999 – May 2007
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1947 (ọmọ ọdún 76–77)
Lokoja, Kogi State, Nigeria

Jonathan Tunde Ogbeha je Ogagun nibi Ise Ologun ile Naijiria to tifeyinti lati ipinle Kogi, o je olumojuto/gomina ologun fun ipinle Akwa Ibom ati leyin re fun Ipinle Bendel nigba ijoba ologun Ogagun Ibrahim Babangida (1985-1993). Leyin ti oselu pada ni 1999 o je didiboyan gege bi alagba fun Iwoorun Kogi ni Ile-igbimo Asofin Naijiria lati May 1999 titi di May 2007.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]