Husaini Abdullahi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Husaini Abdullahi
Hussaini Abdullahi
Gomina Ipinle Bendel
In office
March 1976 – July 1978
AsíwájúGeorge Agbazika Innih
Arọ́pòAbubakar Waziri
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1939-03-03)Oṣù Kẹta 3, 1939
Aláìsí9 July 2019(2019-07-09) (ọmọ ọdún 80)
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
(Àwọn) olólùfẹ́Doma LGA, Nasarawa State of Nigeria

Husaini Abdullahi

Wọ́n bí Abdullahi ní ọjọ́ Kẹ́ta Oṣù Kẹ́ta, ọdún 1939,(3, March 1939-9 July 2019). Òun ni Ọ̀gágun Àgbà Awoko-Ogun (tfyt), tí Ó sì fìgbà kan jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Bendel, tẹ́lẹ̀ nílẹ̀ Nàìjíríà látlati oṣù kẹ́ta ọdún 1976 sí oṣù Kéje ọdún 1978 nígbà ìṣèjọba Ológun Ọ̀gágun Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́.[1]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Nigeria States". WorldStatesmen. Retrieved 2010-04-19.