Adebayo Lawal
Appearance
Adebayo Hamed Lawal | |
---|---|
Military Governor of Benue State | |
In office July 1978 – 1 October 1979 | |
Asíwájú | Abdullahi Shelleng |
Arọ́pò | Aper Aku |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kẹ̀sán 1941 Offa, Kwara State, Nigeria |
Adebayo Hamed Lawal (born 14 September 1941 o si ku ni Oṣu Karun ọjọ 23, Ọdun 2024) je omo ologun orile-ede Naijiria to ti feyinti ati Gomina Ipinle Benue tele lati July 1978 de October 1979.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Adebayo je oga adari awon omo ologun labe ijoba olusegun obasanjo.