George Akume

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
George Akume
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Benue
In office
Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 1999 – Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 2007
AsíwájúDominic Oneya
Arọ́pòGabriel Suswam
Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Nàìjíríà
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 2007
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí27 Oṣù Kejìlá 1953 (1953-12-27) (ọmọ ọdún 70)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress (APC)

George Akume (bíI Ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀ Oṣù kejìlá Ọdún 1953) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Benue tẹ́lẹ̀. Òhun ni ààrẹ Ile-igbimo Asofin Naijiria tí ó sì jẹ́ aṣojú fún abasoju Àríwá-ìwòorùn Benue láti Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 2007. [1] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Action Congress of Nigeria.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Uja Emmanuel, Makurdi and Yusufu Aminu (2011-04-28). "Benue youths protest governorship poll result". The Nation. Retrieved 2011-05-02.