Bello Mohammed Tukur

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Bello Mohammed Tukur
Aṣojú àárín Adamawa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
Oṣù karún Ọdún 2011
Asíwájú Jubril Aminu
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ẹgbẹ́ olóṣèlú People's Democratic Party (PDP)

Bello Mohammed Tukur jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àárín Adamawa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2011 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party.[1][2][3][4][5]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]