David Mark

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
David Alechenu Bonaventure Mark
Davidmark81.jpg
Ààrẹ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà
Assumed office
Ọjọ́ kẹfà Oṣù kẹfà Ọdún 2007
Deputy Ike Ekweremadu
Preceded by Ken Nnamani
Constituency Gúúsù Benue
Ààrẹ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.
Assumed office
Oṣù kẹrin Ọdún 2003
Gómínà Ìpínlẹ̀ Niger
In office
Oṣù kínín 1984 – 1986
Preceded by Awwal Ibrahim
Succeeded by Garba Ali Mohammed
Personal details
Born Oṣù kẹrin 1948
Zungeru, Niger State[1]
Nationality Ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Political party PDP

David Alechenu Bonaventure Mark (bíi ní Oṣù kẹrin Ọdún 1948) jẹ́ ológun tí ó ti fẹ̀hìntì àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Ìpínlẹ̀ Benue ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[3] Ó jẹ́ ààrẹ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin.[4][5]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Zungeru: The abandoned first capital city of Nigeria". Nigerian Tribune online (African Newspapers of Nigeria). 2007-10-28. http://www.tribune.com.ng/28102007/features.html. Retrieved 2007-11-03. 
  2. Nkwazema, Stanley; Chuks Okocha and Juliana Taiwo (2007-11-02). "House Defies PDP, Elects Bankole Speaker". Thisday online (Leaders & Company). http://www.thisdayonline.com/nview.php?id=94039. Retrieved 2007-11-03. 
  3. "Senator David Mark". National Assembly of Nigeria. Archived from the original on 2007-09-25. Retrieved 2007-11-03. 
  4. "Childhood". Senate President. Retrieved 7 May 2012. 
  5. "Benue: David Mark in controversial re-election win". New Nigerian Politics. 10 April 2011. http://newnigerianpolitics.com/2011/04/10/benue-david-mark-in-controversial-re-election-win/. Retrieved 7 May 2012.