Teslim Folarin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Teslim Folarin
Alagba fun Aringbangan Oyo
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
29 May 2007
Asíwájú Brimmo Yusuf
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí October 1963
Oyo State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlú PDP

Teslim Folarin (ojoibi October 1963) je Alagba ni Ile Alagba Asofin Naijiria lati 2003 de 2007.

Esun isekupani[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni 4 January, 2011 Oloopa Naijiria fesun kan Folarin ati awon meta miran, Ramoni Jayeoba, Bankole Olaide Raji ati Raimi Ismaila pe won lowo ninu iku Eleweomo,[1][2] to je olori egbe kan NURTW eka Ipinle Oyo.

Ni 13 January 2011, Oloopa Naijiria fagile esun isekupani ti won fi kan bi be Ile-Ejo ni Ibadan tu sile kuro latimole.[3]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]