Ovie Omo-Agege
Ìrísí
Ovie Omo-Agege | |
---|---|
Deputy President of the Nigerian Senate | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 11 June 2019 | |
Ààrẹ | Ahmed Ibrahim Lawan |
Asíwájú | Ike Ekweremadu |
Nigerian Senator for Delta | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga May 2011 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 23 Oṣù Kẹjọ 1963 Orogun, Ughelli North Local government area, Delta State, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress (APC) |
Residence | Abuja, Nigeria |
Alma mater | University of Benin |
Profession | Lawyer, politician |
Obarisi Ovie Omo-Agege tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1953 (23rd August 1953) jẹ́ amọ̀fin, olóṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Delta lorílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni Igbákejì-Ààrẹ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin àgbà ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti asojú agbègbè àárín Delta ní ilé Ìgbìmò Asòfin láàrin ọdún 2015 sí 2023.[1] Wọ́n dìbò yàn án gẹ́gẹ́ bí Igbákejì Ààrẹ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin àgbà ti Nàìjíríà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress(APC), lọ́jọ́ kọkànlá oṣù kẹfà ọdún 2019 nígbà tí ó borí alátakò rẹ̀, Ike Ekweremadu, tí ẹgbẹ́ òṣèlú People’s Democratic Party, PDP. Omo-Agege ni aṣòfin àgbà àkọ́kọ́ láti ìpínlẹ̀ Delta tí ó dórí òye òṣèlú yìí. [2][3]
Otún le ka
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "APC‘ll produce next President, Omo-Agege boasts". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-02-17. Retrieved 2022-03-16.
- ↑ "BREAKING: Omo-Agege Defeats Ekweremadu To Emerge Deputy Senate President". Channels Television. Retrieved 2019-06-11.
- ↑ Breaking : Senator Ovie Omo-Agege Elected Nigeria 9th Assembly Deputy Senate President More Details : https://ejesgist.com/breaking-senator-ovie-omo-agege-elected-nigeria-9th-assembly-deputy-senate-president.html