Jump to content

Orji Uzor Kalu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Orji Uzor Kalu
7th Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia
In office
May 29, 1999 – May 29, 2007
AsíwájúAnthony Obi
Arọ́pòTheodore Orji
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí21 Oṣù Kẹrin 1960 (1960-04-21) (ọmọ ọdún 64)
Abia State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (1st and 2nd terms). Formed Progressive Peoples Alliance(PPA) as a political party in July 2006 and contested as the party's presidential candidate in 2007.

Orji Uzor Kalu (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹrin ọdún 1960) jẹ́ olóṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Abia lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ṣáà méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ló lò gẹ́gẹ́ bí Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia. Lọ́dún 2019, ó díje dùpò Sínétọ̀ lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, ó sìn wọlé. Lọ́jọ́ karùn-ún oṣù Kejìlá ọdún 2019, ilé ẹjọ́ dá a lẹ́bi ẹsùn jìbìtì owó tí ìjọba àpapọ̀ fi kàn án, wọ́n sì fi i sẹ́wọ̀n ọdún méjìlá gbáko. [1]




Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Orji Uzor Kalu gets 12 years imprisonment - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 2019-12-05. Retrieved 2019-12-05.