Bola Tinubu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Bola Tinubu
Asiwaju Bola Ahmed Tinubu (5980497975).jpg
12th Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó
In office
May 29, 1999 – May 29, 2007
AsíwájúBuba Marwa (military admin.)
Arọ́pòBabatunde Fashola
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíOṣù Kẹta 29, 1952 (1952-03-29) (ọmọ ọdún 70)
Lagos State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress
OccupationPolitician

Bọ́lá Ahmed Tinúbú (ọjọ́ọ́ ìbí 29 March, 1952) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, òun sì ni Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó nígbà kan rí láti ọdún 29 May odun 1999 títí di ọdún 29 May, 2007.[1] Àwọn ará ìlú ti kọ́kọ́ dìbò yàn Bola Ahmed Tinubu láti di Sẹ́nétọ̀ ní ọdún 1992 àmọ́ wọ́n fagilé ìbò náà ní ọdún (12 June, 1993)[2]

Kíkéde ète láti dupò ààre[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ojo kokanla, osù kíní, odun 2022(January 11, 2022), Bola Ahmed kede ète rè láti dupo ààre Nàìjíríà ní odún 2023 lábé egbé oselu All Progressives Congress(APC).[3] Ni ojo kejo osu kefa odun 2022, Tinubu jawe olubori ninu idibo aare ninu egbe oselu All Progressive Congress pelu ami ayo 1271, lati bori Igbakeji Aare Yemi Osinbajo ati Rotimi Amaechi ti o gba 235 ati 316 leralera.[1][4]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Bola Ahmed Tinubu - Profile". Africa Confidential. 2019-10-07. Retrieved 2019-10-07. 
  2. "'Tinubu Died At A Time Nigeria, Lagos Needed His Wealth Of Experience', Sanwo-Olu Says Of Ex-Lagos Head Of Service". Sahara Reporters. 2019-09-06. Retrieved 2019-10-07. 
  3. Daka, Terhemba; (Abuja), Adamu Abuh; Harcourt), Ann Godwin (Port; (Yenagoa), Julius Osahon; (Ibadan), Rotimi Agboluaje (2022-01-11). "Tinubu confirms presidential ambition: I’m a kingmaker, I want to be king - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved 2022-04-27. 
  4. Akoni, Olasunkanmi (June 11, 2022). "APC: Why Tinubu is yet to visit pan Yoruba, Igbo groups - Aide". Vanguard News. Retrieved June 12, 2022.