Bọ́lá Tinúbú
Bola Tinubu | |
---|---|
12th Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó | |
In office May 29, 1999 – May 29, 2007 | |
Asíwájú | Buba Marwa (military admin.) |
Arọ́pò | Babatunde Fashola |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Kẹta 1952 Lagos State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressive Congress |
Occupation | Politician |
Bọ́lá Ahmed Tinúbú (ọjọ́ ìbí Ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù Kẹ́ta, ọdun 1952) jẹ́ Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nigeria tí wọ́n ṣe ìbúra fún lọ́jọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2023 lẹ́yìn tí ó jáwé olúborí nínú ìdìbò ààrẹ ọdun 2023.[1] Ó jẹ́ Gómìnà-àná Ìpínlẹ̀ Èkó láàrin ọdún 29 May odun 1999 títí di ọdún 29 May, 2007.[2] Àwọn ará ìlú ti kọ́kọ́ dìbò yàn Bola Ahmed Tinubu láti di Sẹ́nétọ̀ ní ọdún 1992, àmọ́ wọ́n fagilé ìbò náà ní ọdún (12 June, 1993)[3]
Kíkéde ète láti dupò ààre
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọjọ́ kọkànlá, oṣù kíní, ọdún 2022(January 11, 2022), Bola Ahmed kéde ète rẹ̀ láti dupò ààrẹ Nàìjíríà ní odún 2023 lábé ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress(APC).[4] Ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹfà ọdún 2022, Tinubu jáwé olúborí nínú ìdìbò-abẹ́lé ààrẹ nínú ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress(APC) pẹ̀lú àmì ayò 1271, láti borí Igbákejì Ààrẹ Yẹmí Ọ̀ṣínbàjò àti Rotimi Amaechi tí ó gba 235(Osinbajo) àti 316(Rotimi).[5][6]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Majeed, Bakare (2023-05-29). "PROFILE: Bola Tinubu: The Kingmaker becomes Nigeria's President, 16th Leader". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-29.
- ↑ "Bola Ahmed Tinubu - Profile". Africa Confidential. 2019-10-07. Retrieved 2019-10-07.
- ↑ "'Tinubu Died At A Time Nigeria, Lagos Needed His Wealth Of Experience', Sanwo-Olu Says Of Ex-Lagos Head Of Service". Sahara Reporters. 2019-09-06. Retrieved 2019-10-07.
- ↑ Daka, Terhemba; (Abuja), Adamu Abuh; Harcourt), Ann Godwin (Port; (Yenagoa), Julius Osahon; (Ibadan), Rotimi Agboluaje (2022-01-11). "Tinubu confirms presidential ambition: I’m a kingmaker, I want to be king - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 2022-05-02. Retrieved 2022-04-27.
- ↑ AFP, Le Monde avec (2022-06-08). "Présidentielle au Nigeria : l’ancien gouverneur de Lagos, Bola Tinubu, remporte la primaire du parti au pouvoir". Le Monde.fr (in Èdè Faransé). Retrieved 2023-04-01.
- ↑ Akoni, Olasunkanmi (June 11, 2022). "APC: Why Tinubu is yet to visit pan Yoruba, Igbo groups - Aide". Vanguard News. Retrieved June 12, 2022.