Jump to content

Gbolahan Mudasiru

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gbolahan Mudasiru
Gbolahan Mudasiru

Gbolahan Mudasiru(eni ti a bi ni 18 October 1945[1] ti o si fayesile ni 23 September 2003) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀.[2] O jé Gomina ipinle Èkó laarin Osu kinni odun 1984 si osù kejo odun 1986 nígba isejoba ologun Muhammadu Buhari àti Ibrahim Babangida.[3]



  1. Africa Ìkọ kedereWho's who. 1991. ISBN 9780903274173. https://books.google.com/books?id=9EAOAQAAMAAJ&q=Gbolahan+Mudasiru+October+18,+1945. 
  2. Afisunlu, Feyi (2013-05-28). "Former Lagos state First Lady, Foluke Mudashiru passes on". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-07. 
  3. "Nigerian States". WorldStatesmen. Retrieved 2010-05-01.