Babajide Sanwo-Olu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Babajide Olusola Sanwo-Olu
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́University of Lagos
Lagos Business School
John F. Kennedy School of Government
London Business School
Iṣẹ́Banker, Politician
Political partyAll Progressives Congress
Opponent(s)Jimi Agbaje

Babájídé Olúṣọlá Sanwó-Olú (ojoibi 29-05-1965) jẹ́ olóṣèlú àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó to wà lórí àléfà lọ́wọ́́lọ́wọ́. Wọ́n dìbò yàán- gẹ́gẹ́ bí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 2019 lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú APC.[./https://en.wikipedia.org/wiki/All_Progressives_Congress All Progressives Congress] leyin ti Gomina-ana ipinle Eko, Akinwunmi Ambode jakule ninu idibo abele egbe All Progressive Congress. [1] [2] [3] [4]

Sanwo-Olu ní Ìwé-ẹ̀rí Bsc àti MBA láti Yunifásítì ìlú Èkó. Ó jẹ akọle ti Ile -iwe giga ti John F. Kennedy , Ile -iṣẹ Ikọja- ilu London ati Ile- iṣẹ Ikọja Lagos . [5]


Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]