Owó

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Owó ni ohunkóhun tí àwọn ènìyàn kan bá gbà lágbègbè, ìlú tàbí orílẹ̀-èdè wọn láti máa fi ṣe kárakára ọjà tàbí san gbèsè. Ó jẹ́ ohunkóhun tàbí àkọsílẹ̀ tó dájú tí gbogbo ènìyàn gbà láti máa fi san fún ọjà rírà, iṣẹ́ tí a ṣe fúnni tàbí san gbèsè àti owó-orí. [1] [2] [3] Àwọn onímọ̀ ṣàlàyé pàtàkì Owó gẹ́gẹ́ bí ohun tí a fi ń ṣe pàṣípàrọ̀ ọ̀jà, nǹkan-ìdíyelọ́jà, nǹkan-ìdíyelé dúkìaí, àti nǹkan ipààlà iye ọjà. Ohunkóhun tí ó bá lè ṣe àwọn nǹkan wọ̀nyí ni a lè kà sí Owó.[4][5]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Investopedia (2017-04-26). "What Is Money?". Investopedia. Retrieved 2019-10-08. 
  2. "What is money? definition and meaning". BusinessDictionary.com. 2019-10-03. Retrieved 2019-10-08. 
  3. "Definition of MONEY". Definition of Money by Merriam-Webster. 2019-05-28. Retrieved 2019-10-08. 
  4. "Functions of Money". cliffsnotes.com. Retrieved 2019-10-08. 
  5. "Top 6 Functions of Money –Discussed". Economics Discussion. 2015-10-17. Retrieved 2019-10-08.