Akínwùnmí Àḿbòdé

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Akínwùnmí Aḿbọ̀dé (tí a bí ní Ọ̣jọ́ Kẹrìnlá Oṣù Kẹfà Ọdún 1963) ni Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó ti fìgbà kan jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba fún ọdún mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n. Ó jẹ́ Olùgbaninímọ̀ràn lórí ìsúnná owó kí ó tó wá díje dupò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 2015.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]