Jìmí Agbájé

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Jimi Agbaje)
Jimi Agbaje

Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí2 Oṣù Kẹta 1957 (1957-03-02) (ọmọ ọdún 67)
Lagos, Lagos State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeoples Democratic Party (PDP)
(Àwọn) olólùfẹ́Abiola Agbaje (née Bankole) (1982–present)
Alma materSt Gregory's College, Lagos
University of Ife (now Obafemi Awolowo University)
OccupationPharmacist, Politician
Websitejimiagbaje.com
Nickname(s)JK or Jay Kay

Olújìmí Kọ́láwọlé Agbájé (tí à ń pè ní Jìmí Agbájé, tí a bí ní Ọjọ́ kejì oṣù kẹta ọdún 1957 (March 2, 1957), jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ olóògún òyìnbó àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó díje dú ipò Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 2015 àti 2019 lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́-òṣèlú People's Democratic ṣùgbọ́n ó pàdánù gbogbo rẹ̀. [1][2].

Ìgbà èwe àti aáyan ìṣèlú rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Jìmí Agbájé ní Ọjọ́ kejì oṣù kẹta ọdún 1957 ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Orúkọ àwọn òbí rẹ̀ ni Olóyè Julius Kòṣebínú (Banker) àti Ìyáàfin Margaret Ọlábísí (oluko) Agbájé. Òun ọmọ ìkejì tí àwọn òbí rẹ̀ bí, àkọ́bí ọmọ wọn ní ṣẹ́gun Agbájé, tí ó jẹ́, Alákòóso ilé ìfowópamọ́, Guaranty Trust Bank.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Isawade, Isa (2019-01-21). "Countdown to 2019: Profile of the PDP Lagos governorship candidate, Jimi Agbaje". P.M. News. Retrieved 2019-09-17. 
  2. Published (2015-12-15). "Agbaje". Punch Newspapers. Retrieved 2019-09-17.