Jump to content

Order of the Niger

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Infobox order

The order takes its name from the River Niger

Nàìjíríà gba olómìnira ní ayájọ́ ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá 1960, ó sì di orílẹ̀-èdè olómìnira ní ọdún 1963. Orílẹ̀-èdè yí ṣe agbékalẹ̀ amì-ẹ̀yẹ ìdánilọ́lá méjì kan kalẹ̀ láti ma fi bu ọlá fún àwọn lààmì-laaka ènìyàn láwùjọ. Àwọn àmì-ẹ̀yẹ náà ni: Order of the Niger àti Order of the Federal Republic.[1]

Àmì-ẹ̀yẹ GCON

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn amì-ẹ̀yẹ méjì tí wọ́n lákaakì jùlọ nínú àwọn amì-ẹ̀yẹ náà ni: Grand Commander in the Order of the Federal Republic . Ìsọ̀rí àkọ́kọ́ yí jẹ́ amì-ẹ̀yẹ tí ó tọ́ sí ẹnikẹ́ni tí ó bá ti jẹ Ààrẹ àti igbákejì Ààrẹ, Olórí ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin, Adájọ́ Àgbà fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.


Ìsọ̀rí amì-ẹ̀yẹ náà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kọ́ṣe ìjọba ìjọba àmúnisìn ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì nípa fífi amì-ẹ̀yẹ da àwọn lààmì-laaka àti ọ̀tọ̀kùlú ìlú lọ́lá. Amì-ẹ̀yẹ yí ni ó wà fún àwọn ológun àti àwọn tí kìí ṣe ológun. Wọ́n sì ma ń kọ̀wé ránṣẹ́ sí àwọn tí wọ́n bá yàn láti fi amì-ẹ̀yẹ náà dá lọ́lá.

  • Grand Commander of the Order of the Niger (GCON)
  • Commander of the Order of the Niger (CON)
  • Officer of the Order of the Niger (OON)
  • Member of the Order of the Niger (MON)

Àwọn tí wọ́n ti amì-ẹ̀yẹ náà rí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

[2]

S/NO Orúkọ Ipò Sector Irúfẹ́ amì-ẹ̀yẹ
1 Joseph Wayas Former Senate President Public GCON
2 Aliko Dangote Chairman of Dangote Group Private GCON
3 Bello Maitama Yusuf Former Internal Affairs Minister Public GCON
4 Aminu Tambuwal Speaker House of Representatives, Governor of Sokoto State Public CFR
5 Mohammed Bello Adoke, SAN Attorney General of the Federation Public CFR
6 Oluseyi Petinrin Chief of Defence Staff Public CFR
7 Muhammadu Dikko Chief of Air Staff (CAS) Public CFR
8 Azubuike Ihejirika Chief of Army Staff Public CFR
9 Hafiz Ringim Former Inspector General of Police Public CFR
10 Abdullahi Dikko Former Comptroller General of Police Public CFR
11 Aloma Mariam Mukhtar Former Justice of the Supreme Court Public
12 Victoria Gowon Former First Lady of Nigeria Public CFR
13 Bolaji Akinyemi Scholar, diplomat, former minister Public CFR
14 Chinua Achebe Scholar, eminent writer Private CFR
15 Folagbade Olateru Olagbegi III The Olowo of Owo Private CFR
16 Tony Elumelu Philanthropist Private CON
17 Ahmed Idris Wase Deputy Speaker House of Representatives Public CON
18 Oba Otudeko Business Private CON
19 Akin Mabogunje Consultant, business Private CON
20 Peter Obi Former Governor of Anambra State Public CON
21 Liyel Imoke Former Governor of Cross River State Public CON
22 Adams Oshiomhole Former Governor of Edo State Public CON
23 Patrick Ibrahim Yakowa Former Governor of Kaduna State Public CON
24 Ibrahim Shehu Shema Former Governor of Katsina Staff Public CON
25 Mu'azu Babangida Aliyu Former Governor of Niger State Public CON
26 Rotimi Amaechi Former Governor of Rivers State Public CON
27 Godswill Akpabio Former Governor of Akwa Ibom State Public CON
28 Sule Lamido Former Governor, Jigawa State Public CON
29 Abba Kyari Former Governor North Central State Public CON
30 Chukwuemeka Ezeife Former Governor Anambra Staff Public CON
31 Olusegun Agagu Former Governor of Ondo State, geologist Public CON
32 Isiaka Adeleke Former Governor of Osun State, Senator Public CON
33 Lam Adesina Former Governor of Oyo State Public CON
34 Bukar Abba Ibrahim Former Governor of Yobe State, Senator Public CON
35 Rufus Ada George Former Governor of Rivers State Public CON
36 Atedo Peterside Banker Private CON
37 Sam Ohuabunwa Pharmacist, industrialist, administrator Private OFR
38 Tony Ezenna Business, industrialist Private OFR
39 Iyorwuese Hagher Former Minister of State for Health/Power and Steel and Ambassador to Mexico and High Commissioner to Canada[3] Public OON
40 Victor Olaiya Musician Private[4][5] OON
41 Francesca Yetunde Emanuel Former permanent secretary Public CON
42 Stella Oduah Former Minister of Aviation Public OON
43 Tobi Amusan Athlete Sport OON
44 Iyin Aboyeji Former CEO, Flutterwave & Co-founder, Andela Private OON
45 Teni Teni Private MON
46 Emeka Okwuosa Chairman/GCEO, OilServ Limited Private CON

Àwọn itọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "National Honours Act" (PDF). Policy and Legal Advocacy Centre. Archived from the original (PDF) on 25 April 2015. Retrieved 24 November 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Full list of 2010 and 2011 Nigeria National Honours Award recipients". Ogala.wordpress.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2011-11-14. Archived from the original on 2019-02-02. Retrieved 2019-02-01.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Office of the Pro-Chancellor | Afe Babalola University". Archived from the original on 2021-10-03. Retrieved 2020-08-23.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Victor Olaiya: Nigeria's 'evil genius' trumpeter who influenced Fela Kuti Archived 2021-05-31 at the Wayback Machine., BBC, 21 March 2020
  5. Victor Olaiya, Veteran Highlife Musician Dies At 89 Archived 2021-08-29 at the Wayback Machine., Daily Independent, 12 February 2020

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]