Jump to content

Joseph Wayas

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Dr.Joseph Wayas
President of the Senate of Nigeria
In office
1 October 1979 – 31 December 1983
AsíwájúNwafor Orizu (1966)
Arọ́pòIyorchia Ayu (1992)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1941-05-21)21 Oṣù Kàrún 1941
Obudu, Southern Region, British Nigeria
(now Obudu, Cross River State, Nigeria
Aláìsí30 November 2021(2021-11-30) (ọmọ ọdún 80)
London, England, UK
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPDP

Joseph Wayas (tí wọ́n bí ní 21 May 1941 tó sì dágbére fáyé ní 30 November 2021[1]) fìgbà kan jẹ́ olórí ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà tí orílẹ́-èdè Nàìjíríà lásìkò tí Nàìjíríà gba òmìnira lọ́wọ́ ìjọba ológun(1979–1983).

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Wayas ní Basang, Obudu, ìpínlẹ̀ Cross River ní 21st, May 1941, ó sì kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní Dennis Memorial Grammar School, ní Onitsha. Ó lọ́ sí òkè-òkun níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Higher Tottenham Technical College, London, the West Bronwich College of Commerce, Science and Technology, Birmingham and Aston University, Birmingham. Nígbà tí ó padà dé orílẹ́-èdẹ̀ Nàìjíríà, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gé bí i alámòójútó àti olùdarí láàárín ọdún 1960-1969 fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ilé-iṣé ní orílẹ́-èdè Nàìjíríà àti òkè-òkun.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Joseph Wayas, former senate president, is dead
  2. "Senator Joseph Wayas President of the Senate Federal Republic of Nigeria (1979-1983)". Federal Ministry of Information and Communications, Nigeria. Archived from the original on 18 March 2012. Retrieved 28 February 2010.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)