Victor Olaiya

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Victor Abímbọ́lá Ọláìyá tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Dr. Victor Ọláìyá ni wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1930, ó sìn jáde láyé lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kejì ọdún 2020 [1] (31st December 1930 - 12th February 2020) jẹ́ gbajúmọ̀ afọnfèrè-kọrin afẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun bàbá gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò, Moji Ọláìyá tí ó ṣe aláìsí lọ́dún 2017.[2] [3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Idowu, Ronke (2020-02-12). "Veteran Singer Victor Olaiya Is Dead". Channels Television. Retrieved 2020-02-12. 
  2. Djouls (2009-05-26). "Victor Olaiya's All Stars Soul International". ParisDjs. Retrieved 2020-02-12. 
  3. "Account Suspended". Account Suspended. Retrieved 2020-02-12. 

http://www.thisdayonline.com/archive/2004/04/24/20040424plu01.html