Chinua Achebe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Chinua Achebe
Chinua Achebe (2008)
Ọjọ́ ìbíAlbert Chinualumogu Achebe
(1930-11-16)16 Oṣù Kọkànlá 1930
Ogidi, Anambra
Ọjọ́ aláìsí21 March 2013(2013-03-21) (ọmọ ọdún 82)
Boston, Massachusetts, United States
Iṣẹ́David and Marianna Fisher University Professor and professor of Africana studies Brown University
Ọmọ orílẹ̀-èdèDemographics of Nigeria
Ìgbà1958–2013
Notable worksThe African Trilogy:
Things Fall Apart,
No Longer at Ease,
Arrow of God;
Also, A Man of the People, and
Anthills of the Savannah.

Chinua Achebe (play /ˈɪnwɑː əˈɛb/,[1] oruko abiso Albert Chinualumogu Achebe, 16 November 1930 – 21 March 2013)[2] jẹ́ ọmọ orile ede Naijiria lati eya Igbo ni apa ila oorun Naijiria. Ojogbon ninu imo ikowe (literature) ni Achebe je, opo ni ile Afrika ni won si mo Achebe gege bi okan ninu awon omowe (intellectual) pataki ti a jade ni ile Afrika. Iwe re Igbesiaye Okonkwo (Things fall apart) ni o je eyi ti o gbajumo julo ni ile Afrika leyi igba ti a ti seyipada re si ogun logo ede ka kiri aye.

Igbèsi Àyè Àràkunrin naa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Chinua Achebe ni a bini óṣu November ni ọdun 1930 si church ti Saint Simon, Nneobi ti wọn si wẹ si mimọ gẹgẹbi Albert Chinualumogu Achebe. Baba rẹ̀ Isaiah Okafo Achebe jẹ ólúkọ ati evangelist ti Iya rẹ Janet Anaenechi Iloegbunam jẹ àgbẹ ati ólóri ijọ awọn óbinrin ninu church[3][4][5].

Achebe fẹ Christie ni ọjọ kẹwa óṣu September ọdun 1961 ni Chapel of Resurrection ni ilè iwè giga ti ibadan ti wọn si bi ọmọ óbinrin kan Chinelo (a bini óṣu July, ọdun 1962) ati ọmọ ọkunrin mèji Ikechukwu (à bini óṣu December, ọdun 1964) ati Chidi (a bini óṣu May, ọdun 1967)[6].

Achebe ku ni óṣu March, ọdun 2013 si Boston, Massachusetts, US ti wọn sin si ilú rẹ ni ogidi[7][8].

Ẹkọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni ọdun 1936, Achebe lọsi ilè iwè St Philips ti apapọ ni Akpakaogwe lẹyin naa lo lọsi Ilè iwè ti ijọba ni Umuahia ni ipinlẹ Abia. Ni ọdun 1942, Achebe lọsi Ilè iwè ti Nekede apapọ[9].

Ni ọdun 1948, Achebe lọsi ilè iwè giga ti ilú ibadan lati kẹẹkọ lóri imọ iṣègun ṣugbọn o fi silẹ lati kẹẹkọ lori imọ èdè gẹẹsi, itan ati theology[10].

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]