Aloma Mariam Mukhtar

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Aloma Mariam Mukhtar
13k Olùdájọ́ Àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
16 July 2012
Asíwájú Dahiru Musdapher
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 20 Oṣù Kọkànlá 1944 (1944-11-20) (ọmọ ọdún 72)
Kano, Ipinle Kano, Naijiria

Aloma Mariam Mukhtar (ojoibi November 20, 1944 ni Kano) ni Oludajo Agba Ile-Ejo Gigajulo ile Naijiria lati ojo 16 osu Keje 2012[1]. O ropo oludajo Dahiru Musdapher to feyinti. Ohun ni oludajo agba obinrin akoko ni Naijiria[2].


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]