Adetokunbo Ademola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adetokunbo Ademola

Olùdájọ́ Àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà 2k
In office
1958–1972
AsíwájúStafford Foster-Sutton
Arọ́pòTaslim Olawale Elias
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1906-02-01)1 Oṣù Kejì 1906
Aláìsí29 January 1993(1993-01-29) (ọmọ ọdún 86)

Adetokunbo Adegboyega Ademola, KBE, GCON (1 February 1906 - 29 January 1993) jẹ́ adájọ́ àgbà ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ adájọ́ àgbà ile Nàìjíríà tẹ́lẹ̀, àti ọmọ Ọba Ladapo Ademola II, tí ó jẹ́ Aláké ti Ẹ̀gbá tẹ́lẹ̀.[1] [2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. The Times, March 2, 1993.
  2. Coker, Folarin (1972). Sir Adetokunbo Ademola, Chief Justice of the Federation of Nigeria : a biography.. Lagos: Times Press.