Taslim Olawale Elias

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Taslim Olawale Elias
QC LLD CFR GCON
Ààrẹ
Ilé-ẹjọ́ Ìdájọ́ Akáríayé
In office
1982–1985
Igbákejì Ààrẹ
Ilé-ẹjọ́ Ìdájọ́ Akáríayé
In office
1979–1982
Adájọ́
Ilé-ẹjọ́ Ìdájọ́ Akáríayé
In office
1976–1991
AsíwájúCharles D. Onyeama
Arọ́pòPrince Bola Ajibola
Olùdájọ́ Àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà
In office
1972–1975
Agbẹ́jọ́ Àgbà àti Aránṣẹ́ọba fún Ìdájọ́
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Nàìjíríà
In office
1966–1972
Agbẹ́jọ́ Àgbà àti Alákóso Ìdájọ́ 1k
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Nàìjíríà
In office
1960–1966
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1914-11-11)11 Oṣù Kọkànlá 1914
Lagos, Nigeria
Aláìsí14 August 1991(1991-08-14) (ọmọ ọdún 76)
Lagos, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNàìjíríà
Alma materUniversity College, London

(B.A., LL.B, LL.M, Ph.D)
Igbobi College, Lagos

C.M.S. Grammar School, Lagos

Taslim Olawale Elias (November 11, 1914 – August 14, 1991) je oludajo ara Naijiria. O je Aare Ile-Ejo Idajo Akariaye ati Oludajo Agba Ile-Ejo Gigajulo ile Naijiria tele. Bakanna o kopa ninu isodotun ati atunse awon ofin Naijiria.

International Criminal Court (1979). From right: president Sir Humphrey Waldock, vice-president Taslim Olawale Elias


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]