Jump to content

Tobi Amusan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tóbi Amúsàn-án
Amusan in 2019
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ àbísọOluwatobiloba Ayomide Amusan
Ọmọorílẹ̀-èdè Nigeria
Ọjọ́ìbí23 Oṣù Kẹrin 1997 (1997-04-23) (ọmọ ọdún 27)
Ijebu Ode, Nigeria[1]
Ẹ̀kọ́University of Texas at El Paso
Alma materOur Lady of Apostles Secondary School, Ijebu-Ode
Height1.56 m[1]
Weight57 kg[1]
Sport
Orílẹ̀-èdè Nigeria
Erẹ́ìdárayáAthletics
Event(s)100 metres hurdles
College teamUTEP Miners
ClubBuka Tigers Athletics Club
Coached byLacena Golding-Clarke[2]

Mika Laaksonen[3]

Buka Tigers Coach
Achievements and titles
National finalsNational Sports Festival 2018
Highest world ranking3
Personal best(s)60 mH: 7.89 s (Albuquerque 2018)[4]
100 m: 11.31 s (El Paso 2018)[4]
200 m: 22.92 s (El Paso 2017)[4]
100 mH: 12.12 s (Eugene, Oregon 2022) WR
Updated on 21 Sept 2019.

Olúwatóbilọ́ba Ayọ̀midé tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Tóbi Amúsàn (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹrin ọdún 1997) jẹ́ Ẹlẹ́sẹ̀ ehoro asáré-díje, pàápàá jù lọ eré orí pápá oníwọ̀n ọlọ́gọ́rùn mítà ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [5][6] Òun ni ó borí nínú ìdíje 2022 World Athletics Championships nínú eré-ìjẹ oníwọ̀n ọlọ́gọ́rùnún mítà, pẹ̀lú àṣeyọrí ìṣẹ́jú àáyá tó kéré jù lọ lágbàáyé, ní ìṣẹ́jú 12.06. Ṣáájú àṣekágbá ère-ìjẹ náà, ní abala tó ṣáájú àṣekágbá, ó ti kọ́kọ́ ṣàṣeyọrí èyí láàárín ìṣẹ́jú-àáyá 12.12 péré, èyí tí ẹnikẹ́ni kò ṣe rí ní gbogbo àgbáyé.[7] Tóbi kópa nínú eré-ìjẹ ti Commonwealth lọ́dún 2018, bẹ́ẹ̀ náà ló kópa nínú ti ilẹ̀ Adúláwò Áfíríkà ti ọdún 2018 bákan náà, bẹ́ẹ̀ náà ló kópa ní African Games ní ẹ̀mejì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, tí ó sìn borí .[2][8] Ó gbé ipò kìíní nínú ìdíje Diamond League Trophy lọ́dún 2021 nínú eré-ìjẹ oníwọ̀n mítà ọgọ́rùn-ún ní ìlú Zurich.

Àwọn ìdíje àgbáyé tí ó ti kópa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
2013 African Youth Championships Warri, Nigeria 2nd 100 m hurdles 24.45
3rd Long jump 5.52 m
2014 World Junior Championships Eugene, United States 100 m hurdles Àdàkọ:AthAbbr
African Youth Games Gaborone, Botswana 2nd 100 m hurdles 13.92
2015 African Junior Championships Addis Ababa 1st 100 m hurdles 14.26
African Games Brazzaville, Republic of Congo 1st 100 m hurdles 13.15
2016 World U20 Championships Bydgoszcz, Poland 5th 100 m hurdles 12.95
Olympic Games Rio de Janeiro, Brazil 11th (sf) 100 m hurdles 12.91
2017 World Championships London, United Kingdom 14th (sf) 100 m hurdles 13.04
2018 World Indoor Championships Birmingham, United Kingdom 7th 60 m hurdles 8.05
Commonwealth Games Gold Coast, Australia 1st 100 m hurdles 12.68
3rd 4 × 100 m relay 42.75
African Championships Asaba, Nigeria 1st 100 m hurdles 12.86
1st 4 × 100 m relay 43.77
Continental Cup Ostrava, Czech Republic 5th 100 m hurdles 12.96
4 × 100 m relay Àdàkọ:AthAbbr 163.3(a)
2019 African Games Rabat, Morocco 1st 100 m hurdles 12.68
World Championships Doha, Qatar 4th 100 m hurdles 12.49
2021 Olympic Games Tokyo, Japan 4th 100 m hurdles 12.60
12th (h) 4 × 100 m relay 43.25
2022 African Championships Port Louis, Mauritius 1st 100 m hurdles 12.57 (w)
1st 4 × 100 m relay 44.45
2022 World Championships Oregon, USA 1st 100 m hurdles 12.06 (w)

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 1.2 "2018 CWG bio". Archived from the original on 1 May 2018. Retrieved 30 April 2018. 
  2. 2.0 2.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named El Paso CWG article
  3. "Raise the Pick: Tobi Amusan". Campus Newsfeed. UTEP. Retrieved 2 May 2019. 
  4. 4.0 4.1 4.2 "Tobi Amusan IAAF profile". IAAF. Retrieved 2 May 2019. 
  5. Ben Efe (5 March 2015). "African juniors: Nigerian athletes full of expectations". Vanguard. Retrieved 15 September 2015. 
  6. "AAG: Nigeria Unleash Track And Field Warriors". Complete Sports. 13 September 2015. Archived from the original on 13 September 2015. Retrieved 15 September 2015. 
  7. "Nigeria's Tobi Amusan sets new world record in 100m hurdles". France 24 (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-07-25. Retrieved 2022-07-25. 
  8. "Obiri and Ta Lou dominate, Samaai defeats Manyonga at African Championships in Asaba| News | iaaf.org". www.iaaf.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-05-03.