Jump to content

Complete Sports

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Complete Sports
Complete Sports logo.jpg
TypeDaily newspaper
FormatBroadsheet
FounderSunny Obazu-Ojeagbase
PublisherComplete Communications Limited
EditorMumuni Alao
Dare Esan
Kazeem Tijani
Editor-in-chiefSunny Obazu-Ojeagbase
General managerLydia Oyekanmi
LanguageEnglish
HeadquartersIsolo, Lagos
Circulation124,000
Sister newspapersSuccessDigest Extra
Official websitecompletesports.com

Complete Sports jẹ́ ìwé-ìròyìn eré-ìdárayá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lójoojúmọ́, ó sì ní orílé-iṣẹ́ rẹ̀ ní Isolo, ìjọba ìbílẹ̀ kan ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Ọdún 1995 ni wọ́n kọ́kọ́ tẹ̀ ẹ́ jáde gẹ́gẹ́ bí ìwé-ìròyìn ti Complete Communications Limited àti pé ó ti di ọ̀kan lára àwọn ìwé-ìròyìn tó pọ̀ jù lọ ní Naijiria.[1] Ìwé-ìròyìn náà dojú dé sí àwọn eré-ìdárayá Naijiria pàápàá àwọn agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà.

Complete Sports ti pín káàkiri orílẹ̀-èdè Naijiria àti díẹ̀ nínú àwọn agbègbè ti Benin àti Cameroon, nítorí náà, ó mu kí ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìwé-ìròyìn tí ó káàkiri jù lọ ní Ìwọ-oòrùn Afirika.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Profile Of Publisher- Complete Sports Magazine In Nigeria". Media Nigeria. 8 November 2012. Retrieved 6 August 2015. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. "About Us". Complete Sports. Retrieved 6 August 2015.