Èkó

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Lagos)
Jump to navigation Jump to search
Lagos
Èkó
LagosNg222.jpg
Flag of Lagos
Flag
Official seal of Lagos
Seal
Map of Lagos Metropolis
Map of Lagos Metropolis
Country  Nigeria
State Lagos State
LGA Lagos Island
Ìtóbi[1]
 • Urban 999.6 km2 (385.9 sq mi)
Agbéìlú (2006 census, preliminary)[2]
 • Density 7,941/km2 (20,569.9/sq mi)
 • Ìgboro 7,937,932
Time zone CET (UTC+1)
Website http://www.lagosstate.gov.ng/

Ilu Èkó tabi Lagos je ilu to tobijulo ni orile-ede Naijiria. Ilu Eko fi igbakan je oluilu Naijiria.

Èkó ni orúko ti awon Yorubá npe ìlú erékùsù ti o ti di olú ìlú ati ibùjoko Ijoba gbogbo-gbòò fun ilè Naijiria ni ojó òní. Ìlú Yoruba ni, ṣugbọ́n orúkọ ti awọn enia agbaiye fi npè é ni eyi ti awọn Òyìnbó Potogi ti o kọ́ bẹ etíkun ilẹ̀ Yoruba wò fun un. Orúkọ náà ni “Lagos”, eyi ti ìtumọ rẹ̀ jasi “adágún” tabi “ọ̀sà”, nitoripe ọ̀sà ni o yi ilu náà ka...

Awon Eya Yoruba ti Awori ni o koko tedo si agbegbe Ilu Eko, labe isakoso ati Itona olori-i won, Olofin, awon Awori koko tedo si erekusu Iddo, lehin igba naa ni won bere si ni wonu-u awon agbegbe yoku Eko lati tedo. Ni senturi k'arun din l'ogun {15th Century}, Ilu Eko, bo si abe isakoso Ijoba Bini. Igba naa ni awon ologun Ilu naa so agbegbe ilu naa ni Eko, eleyii, ti o tumo si [Ibi ti awon Ologun ti n simi} Ni ede Edo/Bini. Gbogbo eleyii sele labe olori awon Bini ni igba naa- Oba Orogba. Leyin ti eyi sele,ni Ijoba Bini fi Baale je oye, lati maa M'ojuto/Se Akoso, ati Gbigba Isakole {Tribute} ilu naa bii agbegbe labe-e Ijoba nla ti Bini. Oba Yoruba akoko ti Ilu Eko je, ni Oba Asipa. Ni odun-un 1472, awon Oyibo Potoki{Portuguese} de si ile Eko, awon Potoki naa ni Oyinbo akoko, ti o maa de Ile -Eko lati Erekusu Orile-ede Yuropu ni igba naa....

Aworon[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Summing the 16 LGAs making up Metropolitan Lagos (Agege, Ajeromi-Ifelodun, Alimosho, Amuwo-Odofin, Apapa, Eti-Osa, Ifako-Ijaiye, Ikeja, Kosofe, Lagos Island, Lagos Mainland, Mushin, Ojo, Oshodi-Isolo, Shomolu, Surulere) as per:
    The Nigeria Congress. "Administrative Levels - Lagos State". Retrieved 2007-06-29. 
  2. Summing the 16 LGAs making up Metropolitan Lagos (Agege, Ajeromi-Ifelodun, Alimosho, Amuwo-Odofin, Apapa, Eti-Osa, Ifako-Ijaiye, Ikeja, Kosofe, Lagos Island, Lagos Mainland, Mushin, Ojo, Oshodi-Isolo, Shomolu, Surulere) as per:
    Federal Republic of Nigeria Official Gazette (15 May 2007). "Legal Notice on Publication of the Details of the Breakdown of the National and State Provisional Totals 2006 Census" (PDF). Retrieved 2007-06-29. 
  • J.F. Odunjo (1969), ÌLÚ ÈKÓ ATI ÌJÈBÚ, Isẹ́ Àtúnyèwò ẹ̀kọ́ nipa ọ̀rọ̀ gbígbàsọ Ojú-ìwé 49-54, Eko Ijinle Yoruba Alawiye, Fun Awon Ile Eko Giga, Apa Keji, Longmans of Nigeria.

Awon ile isimi towa Leko(Lagos Hotels).