Aliko Dangote

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Alhaji
Aliko Dangote
MFR, GCON
Aliko Dangote.jpg
Dangote at the World Economic Forum, 2011
Ọjọ́ìbíAliko Dangote
10 Oṣù Kẹrin 1957 (1957-04-10) (ọmọ ọdún 64)
Kano, Northern Nigeria,
British Nigeria
(now Kano, Nigeria)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Government College, Birnin Kudu
Iléẹ̀kọ́ gígaAl-Azhar University, Cairo
Iṣẹ́Industrialist and philantrophist
Ìgbà iṣẹ́1977—present
Gbajúmọ̀ fúnFounding and leading the Dangote Group
Net worthUS$7.7 billion (April 2020)[1]
Àwọn ọmọ3 daughters including Halima Dangote;

Aliko Dangote GCON (ojoibi 10 April 1957) je onisowo ati olore ara Naijiria to oludasile ati alaga ile-ise Dangote Group, ile-ise aloero gbangba ni Afrika.[2]

Gbogbo ohun ini re to US$8.1 billion (March 2020)[1], ni January 2020, ohun ni eni ololajulo 88k ni agbaye ati eni oloro julo ni ile Afrika.[3]

Ni Oṣu kọkanla ọdun 2021, Sani Dangote, Igbakeji Alakoso (VP) ti Ẹgbẹ Dangote ati aburo Aliko Dangote, ku.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Aliko Dangote". Forbes. Retrieved 16 October 2019. 
  2. "History & Strategy – Dangote Industries Limited" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-15. 
  3. Nsehe, Mfonobong (5 March 2013). "The Black Billionaires 2013". Forbes. Retrieved 3 May 2015.