Jìmí Agbájé
Ìrísí
Jimi Agbaje | |
---|---|
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 2 Oṣù Kẹta 1957 Lagos, Lagos State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Peoples Democratic Party (PDP) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Abiola Agbaje (née Bankole) (1982–present) |
Alma mater | St Gregory's College, Lagos University of Ife (now Obafemi Awolowo University) |
Occupation | Pharmacist, Politician |
Website | jimiagbaje.com |
Nickname(s) | JK or Jay Kay |
Olújìmí Kọ́láwọlé Agbájé (tí à ń pè ní Jìmí Agbájé, tí a bí ní Ọjọ́ kejì oṣù kẹta ọdún 1957 (March 2, 1957), jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ olóògún òyìnbó àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó díje dú ipò Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 2015 àti 2019 lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́-òṣèlú People's Democratic ṣùgbọ́n ó pàdánù gbogbo rẹ̀. [1][2].
Ìgbà èwe àti aáyan ìṣèlú rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Jìmí Agbájé ní Ọjọ́ kejì oṣù kẹta ọdún 1957 ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Orúkọ àwọn òbí rẹ̀ ni Olóyè Julius Kòṣebínú (Banker) àti Ìyáàfin Margaret Ọlábísí (oluko) Agbájé. Òun ọmọ ìkejì tí àwọn òbí rẹ̀ bí, àkọ́bí ọmọ wọn ní ṣẹ́gun Agbájé, tí ó jẹ́, Alákòóso ilé ìfowópamọ́, Guaranty Trust Bank.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Isawade, Isa (2019-01-21). "Countdown to 2019: Profile of the PDP Lagos governorship candidate, Jimi Agbaje". P.M. News. Retrieved 2019-09-17.
- ↑ Published (2015-12-15). "Agbaje". Punch Newspapers. Retrieved 2019-09-17.