Ìpínlẹ̀ Ẹdó

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Edo State)
Jump to navigation Jump to search
Ìpínlẹ̀ Edo
State nickname: Heart Beat of Nigeria
Location
Location of Edo State in Nigeria
Statistics
Governor
(List)
Adams Oshiomhole (AC)
Date Created 27 August 1991
Capital Benin City
Area 17,802 km²
Ranked 22nd
Population
1991 Census
2005 estimate
Ranked 27th
2,159,848
3,497,502
ISO 3166-2 NG-ED
imura omo ilu ipinle Edo

Ìpínlẹ̀ Ẹdó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó sàgbè pẹ̀lú àríwá àti ìwọ̀ oòrùn ìpínlẹ̀ Kogi, àgbè pẹ̀lú gúúsù ìpínlẹ̀ Delta àti ìlà-oòrùn ìpínlẹ̀ Ondo.

Àwọn ìjọba ìbílẹ̀ lábẹ́ rẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìjọba ìbị́lẹ̀ méjìdínlógun ló wà lábẹ́ ìpínlẹ̀ Edo.

 • Akoko-Edo
 • Egor
 • Esan Central
 • Esan North-East
 • Esan South-East
 • Esan West
 • Etsako Central
 • Etsako East
 • Etsako West
 • Igueben
 • Ikpoba-Okha
 • Oredo
 • Orhionmwon
 • Ovia North-East
 • Ovia South-West
 • Owan East
 • Owan West
 • Uhunmwonde

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]