Ìpínlẹ̀ Kwara
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Ipinle Kwara)
Ipinle Kwara State nickname: State of Harmony | ||
Location | ||
---|---|---|
Statistics | ||
Governor (List) |
Abdulrahman Abdulrasaq(APC) | |
Date Created | 27 May 1967 | |
Capital | Ilorin | |
Area | 36,825 km² Ranked 9th | |
Population 1991 Census 2005 estimate |
Ranked 31st 1,566,469 2,591,555 | |
ISO 3166-2 | NG-KW |
Kwara (Yorùbá: Ìpínlẹ̀ Kwárà) jẹ ìpínlẹ̀ ní apá ìwọ̀-oòrùn ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ ni ìlọrin. Ó wà ní àríwá àárín gbùngbùn ti a mò sí ìgbánú àárín ìlú. Yorùbá, pèlú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Nupe, Ìbàrìbá àti Fúlàní díẹ̀ ni wọ́n tẹ̀dó síbẹ.[1]
Ìpínlè kwárà ní ìjoba ìbílẹ̀ mérìndilógún, ìjoba ìpínlè ti ìwò oòrùn Ìlorin ni ènìyàn tó pòjù [2],Won da ipinle kwara sile ni ojo ketadinlogbon 1967 .
Ijọba Ìbílẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Kwara jẹ́ mérìndilógún.[3] Awọn náà ní:
- Asa
- Baruten
- Edu
- Ekiti
- Ifelodun
- Ilorin East
- Ilorin South
- Ilorin West
- Irepodun
- Isin
- Kaiama
- Moro
- Offa
- Oke Ero
- Oyun
- Pategi
Awọn èdè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn orísìrísí èdè tí ó wà ní ìpínlè Kwara nítítò Ijọba ìbílẹ̀:
LGA | Awọn èdè |
---|---|
Asa | Yoruba |
Baruten | Baatonum and Bokobaru |
Edu | Nupe |
Ekiti | Yoruba |
Ifelodun | Yoruba |
Ilorin East | Yoruba |
Ilorin South | Yoruba |
Ilorin West | Yoruba |
Isin | Yoruba |
Irepodun | Yoruba |
Kaiama | Bokobaru |
Moro | Yoruba |
Offa | Yoruba |
Oke Ero | Yoruba |
Ọ̀yun | Yoruba |
Pategi | Nupe |
Àwọn èèyàn jànkànjànkàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- AbdulRahman AbdulRazaq, olóṣèlú
- Bukola Saraki, olóṣèlú
- David Abioye, àlúfà
- Cornelius Adebayo, olóṣèlú
- Femi Adebayo, òsèrékùrin ati olùgbéré-jáde
- Tunde Adebimpe, olórin
- Kemi Adesoye, olukoereoritage
- Abdulfatah Ahmed, oṣiṣẹ ile ifowopamọ ati olóṣèlú
- Simon Ajibola, olóṣèlú
- Mustapha Akanbi, agbéjọ́rò
- Sheik Adam Abdullah Al-Ilory, onímọ̀ àgbà ẹsìn
- Sarah Alade, gómìnà banki apàpò orile-èdè Nàìjíríà teleri
- Lola Ashiru, olóṣèlú
- Adamu Atta, olóṣèlú
- Kunle Afolayan, òsèrékùrin, oludari ere
- Ayeloyun, olórin
- Joseph Ayo Babalola, àlùfáà
- David Bamigboye, ológun(sójà)
- Theophilus Bamigboye, ológun(sójà) atí olóṣèlú
- Salihu Modibbo Alfa Belgore, oludajo ati olori gbogbo adájọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
- Oga Bello, òsèrékùrin ati olùgbéré-jáde
- Ibrahim Gambari, asójú
- Yusuf Gobir, olusakoso
- Rafiu Adebayo Ibrahim, olóṣèlú
- Tunde Idiagbon, ológun (sójà)
- Ahmed Mohammed Inuwa, olóṣèlú
- Joana Nnazua Kolo, kọmísónà fun awon ọ̀dọ́ atí eré ìdárayá
- Farooq Kperogi, oniroyin
- Mohammed Shaaba Lafiagi, olóṣèlú
- Lágbájá, olórin
- Salaudeen Latinwo, ológun (sójà)
- Mohammed Lawal, naval officer
- Lai Mohammed, agbéjọ́rò ati olóṣèlú
- Ibrahim Yahaya Oloriegbe, olóṣèlú
- Abdulkadir Orire, first Grand Khadi of the Kwara State Sharia Court of Appeal
- David Oyedepo, àlúfà
- Wasiu Alabi Pasuma, olórin
- Gbemisola Ruqayyah Saraki, olóṣèlú
- Olusola Saraki, olóṣèlú
- Toyin Saraki, onínúre fun eto ìlera
- Abdulfatai Yahaya Seriki, olóṣèlú
- AbdulRazzaq Ibrahim Salman, àlúfà
- Bola Shagaya, onísówò
- Tony Tetuila, olórin
- Rashidi Yekini, Agbaboolu
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "About Kwara State". Kwara State Government.
- ↑ "Kwara (State, Nigeria)". Population Statistics, Charts, Map and Location. 2016-03-21. Retrieved 2022-03-08.
- ↑ "List Of Local Government Areas In Kwara State And Their Headquarters". OldNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-16. Retrieved 2021-06-20.