Rashidi Yekini

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Rashidi Yekini
Rashidi_Yekini.jpg
Personal information
Ọjọ́ ìbí (1963-10-23)Oṣù Kẹ̀wá 23, 1963
Ibi ọjọ́ibí Kaduna, Nigeria
Ọjọ́ aláìsí Oṣù Kàrún 4, 2012 (ọmọ ọdún 48)


Oṣù Kàrún 4, 2012(2012-05-04) (ọmọ ọdún 48)
Ibi ọjọ́aláìsí Ibadan, Nigeria
Ìga 1.90 m (6 ft 3 in)
Senior career*
Years Team Apps (Gls)
1981–1982 UNTL Kaduna ? (?)
1982–1984 Shooting Stars ? (?)
1984–1987 Abiola Babes ? (?)
1987–1990 Africa Sports ? (?)
1990–1994 Vitória Setúbal 108 (90)
1994–1995 Olympiacos 4 (2)
1995–1996 Sporting Gijón 14 (3)
1997 Vitória Setúbal 14 (3)
1997–1998 Zürich 28 (14)
1998–1999 Bizerte ? (?)
1999 Al-Shabab ? (?)
1999–2002 Africa Sports ? (?)
2002–2003 Julius Berger ? (?)
2005 Gateway 26 (7)
National team
1984–1998 Àdàkọ:Nft 58 (37)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Rashidi Yekini je omo odun mejidinlaaadota (48 yrs.) (23 October 1963 – 4 May 2012) je agbaboolu-elese, elege-ara lowo iwaju omo ile Naijiria. O je eni to gba boolu metadinlogoji Sonu awon nigba ti o n gba boolu fun egbe agbaboolu Vitória de Setúbal ni orile ede potogi gege bi akoko omo orile ede olominira ile Naijiria ti yoo koko gba iru ami ayo bee wole. Bakan naa, lo run soju orile-ede re niniu oniruuru ifesewonse paapaa julo idije ife-agbaye [[(football)| world cups][ ni eyi ti o tun ti gba ami ayo kan soso akoko wole ti eyi si je ami-ayo akoko iru re to orile-ede naa too koko gba wole ninu idije naa. Won fi ami eye eni ti o mo boolu gba julo nile Adulawo | African footballer of the year da lola ni odun 1993.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]