Sẹ̀nẹ̀gàl

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàl
République du Sénégal
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto"Un Peuple, Un But, Une Foi"  (French)
"One People, One Goal, One Faith"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèPincez Tous vos Koras, Frappez les Balafons
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Dakar
14°40′N 17°25′W / 14.667°N 17.417°W / 14.667; -17.417
Èdè àlòṣiṣẹ́ French
Àwọn èdè dídámọ̀ níbẹ̀ Wolof, Soninke, Seereer-Siin, Fula, Maninka, Diola,[1]
Orúkọ aráàlú Ará Sẹ̀nẹ̀gàl
Ìjọba Semi-presidential republic
 -  President Macky Sall
 -  Prime Minister Abdoul Mbaye
Independence
 -  from France 4 April 1960 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 196,723 km2 (87th)
76,000 sq mi 
 -  Omi (%) 2.1
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 12,534,000[2] (72nd)
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 63.7/km2 (137th)
164.9/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $21.773 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $1,739[3] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $13.350 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $1,066[3] 
Gini (1995) 41.3 (medium
HDI (2007) 0.464 (low) (166th)
Owóníná CFA franc (XOF)
Àkókò ilẹ̀àmùrè UTC
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .sn
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 221

Sẹ̀nẹ̀gàl (Faranse: le Sénégal) tabi Orile-ede Olominira ile Senegal je orile-ede ni Iwoorun Afrika. Senegal ni Okun Atlantiki ni iwoorun, Mauritania ni ariwa, Mali ni ilaorun, ati Guinea ati Guinea-Bissau ni guusu. Sinu die lo ku ko yipo Gambia ka patapata si ariwa, ilaorun ati guusu, ibi to se ku nikan ni eti okun Atlanti Gambia[4] Ifesi ile Senegal fe to 197,000 km², be si ni o ni onibugbe bi 13.7 legbegberun.

Dakar ni oluilu re to wa lori Cap-Vert Peninsula ni eti Okun Atlantiki. Bi iye ida kan ninu meta awon ara Senegal ni won n gbe labe ila aini kakiriaye to je US$ 1.25 lojumo.[5]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. « La langue officielle de la République du Sénégal est le Français. Les langues nationales sont le Diola, le Malinké, le Pulaar, le Sérère, le Soninké, le Wolof et toute autre langue nationale qui sera codifiée. » − Extrait du site officiel du gouvernement sénégalais
  2. Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (.PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 "Senegal". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01. 
  4. Gambia lies almost entirely within Senegal, surrounded by it on the north, east and south; from its western coast, Gambia's territory follows the Gambia River more than 300 kilometres (186 miles) inland.
  5. Human Development Indices, Table 3: Human and income poverty, p. 35. Retrieved on 1 June 2009