George Weah

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

George Weah tí àpèjá orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ George Manneh Oppong Weah (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1966) jẹ́ gbajúmọ̀ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá tẹ́lẹ̀ àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Liberia. Òun ni Ààrẹ orílẹ̀-èdè Liberia lọ́wọ́́lọ́wọ́. Wọ́n dìbò yàn án lọ́dún 2018. Kí ó tó di Ààrẹ, jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin-àgbà tí orílẹ̀ èdè náà. Kí ó tó di òṣèlú, ó jẹ́ gbajúgbajà ìlúmọ̀ọ́kà agbábọ́ọ̀lù ṣiṣẹ́. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkọ̀ agbábọ́ọ̀lù ló ti gba bọ́ọ̀lù fún ní òkè-òkun. Àyè agbábọ́ọ̀lù-sáwọ̀n (Striker) ni ó máa ń wà nínú àwọn ọkọ̀ agbábọ́ọ̀lù tí ó ti ṣiṣẹ́.

Àtẹ Àtòjọ ìrìn àjò ìgbésí ayé bọ́ọ̀lù gbígbá rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

George Weah
George Weah - Milan AC 1996-97.jpg
Weah in 1996
25th President of Liberia
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
22 January 2018
Vice President Jewel Taylor
Asíwájú Ellen Johnson Sirleaf
Senator for Montserrado County
Lórí àga
14 January 2015 – 22 January 2018
Asíwájú Joyce Musu Freeman-Sumo
Arọ́pò Saah Joseph[1]
Personal details
Ọjọ́ìbí George Manneh Oppong Weah[2]
1 Oṣù Kẹ̀wá 1966 (1966-10-01) (ọmọ ọdún 53)[3]
Monrovia, Liberia
Ẹgbẹ́ olóṣèlu Coalition for Democratic Change
Height Àdàkọ:Infobox person/height
Spouse(s) Clar Weah
Children 3, including George and Timothy
Residence Executive Mansion
Alma mater DeVry University
George Weah
Personal information
Playing positionStriker
Youth career
1981–1984Young Survivors Claratown
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
1985–1986Bong Range United2(1)
1985–1986Mighty Barrolle10(7)
1986–1987Invincible Eleven23(24)
1987Africa Sports2(1)
1987–1988Tonnerre Yaoundé18(14)
1988–1992Monaco103(47)
1992–1995Paris Saint-Germain96(32)
1995–2000A.C. Milan114(46)
2000Chelsea (loan)11(3)
2000Manchester City7(1)
2000–2001Marseille19(5)
2001–2003Al Jazira8(13)
Total413(194)
National team
1987–2018Liberia53(13)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Menjor, David S. (6 August 2018). "Election: Joseph, Tokpa Replace Weah, Taylor at Senate". Liberian Observer. https://www.liberianobserver.com/news/jospeh-tokpa-replace-taylor-weah-at-senate/. 
  2. Pan, Esther (7 November 2005). "Liberia's Presidential Runoff". Council on Foreign Relations. https://www.cfr.org/backgrounder/liberias-presidential-runoff. Retrieved 28 May 2019. 
  3. "FIFA Magazine – An idol for African footballers". FIFA. Archived from the original on 19 July 2006. Retrieved 6 December 2006. 
  4. "George Weah" (in French). L'Équipe (Paris). https://www.lequipe.fr/Football/FootballFicheJoueur4284.html. Retrieved 28 May 2019.